Ni bo le wa?!

Status
Not open for further replies.

Iya Laje

Well-Known Member
#62
..so ri..omo daadaa ni O..oun ti mo se feran re nu'un.....nitori awon obi'n mi baje...oluware o baa gba ogoji odun lowo re,ti a ba ti ni o wa bawa si'e die bayi,yio seb'aati d'egbe nu'un..nse ni o ma la'ako m'oluware l'ori laarin'gboro..:gnash..sugbon ni eyi ti o ti wa fi iwa re daadaa han mi yi..aaa..o ti fi han wipe..in-fat(infact:D)..O ye kin lo dupe l'owo awon momi re wipe won ko e daadaa ni...sugbon kin to lo..se e o ni aja ni ile yin sha O?smokin:Nitori digbolugi kan ti awon Abike nsin ti le mi ri....
LOL....ese gan ni oo, fun oro idunnu ti e ko yi. E mo wipe won ko wa awa naa tun ara wa ko. Adupe lowo Olorun. A ni aja ni ile wa oo, in-fat....aja naa o ran anyborri.
 

peculiar

Well-Known Member
#64
eyin ara mi, eyin da o? ;) E jowo, se ko si eni ti o ti wo "Riro" ni? Sinima yen, gbankogbi ni o! Abike lo je ki n ranti e lale yi. Maa lo si tiredi lori re laipe yi! Eni ti o ba ti wo, ki e wa so ero yin nipa sinima naa lori tiredi yen o. ;)
 

vince

Well-Known Member
#65
eyin ara mi, eyin da o? ;) E jowo, se ko si eni ti o ti wo "Riro" ni? Sinima yen, gbankogbi ni o! Abike lo je ki n ranti e lale yi. Maa lo si tiredi lori re laipe yi! Eni ti o ba ti wo, ki e wa so ero yin nipa sinima naa lori tiredi yen o. ;)
Ehen!Se wipe ede abinibi wu e so leni,abi,pecs?:spin2:
 

moviewizard

Well-Known Member
#67
Mo sese wo cinima ti won pe ni "Jenifer", osi dun gidi gan, bi igba ti won fi suga si ni. Mo si wo "modupe temi", o si mu opolo lori.
 

peculiar

Well-Known Member
#69
Ehen!Se wipe ede abinibi wu e so leni,abi,pecs?:spin2:

Alagba Finsi, e ku isinmi eni o. Ki ajinde ara ki o ma je tiyin o. :fing33: O ma ma n wa be lekookan ti ede abinibi wa yi ma n wu mi so/ko ni o. :D

Iru eni bayi.......ara mi bale lati ko....o wu mi pe mo ni iwe itan tabi iwe litireso yoruba kan lowo bayi.....ede naa n wu mi ka leni gan!:yellow:
 
Status
Not open for further replies.
Top