Oriki Ounje!

Status
Not open for further replies.

Hubscrown

Well-Known Member
#1
Salute!

Mo gba ounje gbo,
Oun ni Alakoso ara
Iyan l'ounje, Oka L'ogun
Aini rara l'anjeko
K'enun madile ni guguru

Class

Ninu Ipade onje
Iyan l'alaga,
Amala nigba keji
Nijo t'iyan niyawo,
Obe egusi niyawo
Nijo t'amala fe lobinrin,
Ewedu lobinrin
Akara aya Akashu
Moinmoin arewa, Olufe Eko mimu
Dundun ko kere, Ojoba nigberiko
Dodo naa ko rehin, O joba ni ileto
Alagbara ni ata
Alubosa gbajumo
Borokini oloro ni Egusi

Ninu gbogbo eleyi
Ounje daadaa
Omi daadaa
Ategun daadaa
Ni nse ara daadaa.
grinning: :bouncy
http://www.naijarules.com/photo/showphoto.php/photo/2141/what/allfields/name/queen2/name/queen2
 

Oyinkan

Well-Known Member
#5
Hubscrown said:
Salute!

Mo gba ounje gbo,
Oun ni Alakoso ara
Iyan l'ounje, Oka L'ogun
Aini rara l'anjeko
K'enun madile ni guguru

Class

Ninu Ipade onje
Iyan l'alaga,
Amala nigba keji
Nijo t'iyan niyawo,
Obe egusi niyawo
Nijo t'amala fe lobinrin,
Ewedu lobinrin
Akara aya Akashu
Moinmoin arewa, Olufe Eko mimu
Dundun ko kere, Ojoba nigberiko
Dodo naa ko rehin, O joba ni ileto
Alagbara ni ata
Alubosa gbajumo
Borokini oloro ni Egusi

Ninu gbogbo eleyi
Ounje daadaa
Omi daadaa
Ategun daadaa
Ni nse ara daadaa.
grinning: :bouncy
http://www.naijarules.com/photo/showphoto.php/photo/2141/what/allfields/name/queen2/name/queen2
:roll :roll
e fe ran ounje ti ti te fi fun ni oriki:fing05:
 

Hubscrown

Well-Known Member
#6
Oyinkan said:
:roll :roll
e fe ran ounje ti ti te fi fun ni oriki:fing05:
Thats just from childhood memory pass down by old relatives. :excite

I think they got it from their old version of Alawiye yoruba textbook.
 

mealone

Well-Known Member
#11
Hubscrown said:
Salute!

Mo gba ounje gbo,
Oun ni Alakoso ara
Iyan l'ounje, Oka L'ogun
Aini rara l'anjeko
K'enun madile ni guguru

Class

Ninu Ipade onje
Iyan l'alaga,
Amala nigba keji
Nijo t'iyan niyawo,
Obe egusi niyawo
Nijo t'amala fe lobinrin,
Ewedu lobinrin
Akara aya Akashu
Moinmoin arewa, Olufe Eko mimu
Dundun ko kere, Ojoba nigberiko
Dodo naa ko rehin, O joba ni ileto
Alagbara ni ata
Alubosa gbajumo
Borokini oloro ni Egusi

Ninu gbogbo eleyi
Ounje daadaa
Omi daadaa
Ategun daadaa
Ni nse ara daadaa.
grinning: :bouncy
http://www.naijarules.com/photo/showphoto.php/photo/2141/what/allfields/name/queen2/name/queen2
:laugh: have mercy!!
 
Status
Not open for further replies.
Top