Oriki

Status
Not open for further replies.

Oyinkan

Well-Known Member
#1
Oya o, e yin te ba mo oriki ile yii n, oriki adugbo yii n, ati ti ilu yii n o, e wa ma so, e yii afi je ka mo awon omo naijarules to je omo oduduwa ijinle

Oriki Ibadan
Ibadan ile Oluyole,
Ibi t'ole ti n jare oni wun
Omo a fi ka raun fori mu
(e ma blame mi o, mi n sho mo Ibadan)

Oriki Oyo
Oyo a yo mo le sumtin, sumthin, sumthin
 
peculiar

Well-Known Member
#2
Oyinkan said:

woz diz??See this ijinle woman o??Oduduwa ko? ojuju ni! :spin2:
 
Iya Laje

Well-Known Member
#3
Oyinkan said:
Oya o, e yin te ba mo oriki ile yii n, oriki adugbo yii n, ati ti ilu yii n o, e wa ma so, e yii afi je ka mo awon omo naijarules to je omo oduduwa ijinle

Oriki Ibadan
Ibadan ile Oluyole,
Ibi t'ole ti n jare oni wun
Omo a fi ka raun fori mu
(e ma blame mi o, mi n sho mo Ibadan)

Oriki Oyo
Oyo a yo mo le sumtin, sumthin, sumthin
Mayo mayo mayo o lori olumo
mayo mayo mayo o lori olumo
Ibe lo gbe bi mi si o
Ibe lo gbe to mi dagba o
mayo mayo mayo o lori olumo...............
E jo o, emi o mo oriki ile mi o, sugbon mo mo oriki temi, as in ti oruko mi, se mo le so iyen
 
Oyinkan

Well-Known Member
#4
Iya Laje said:

Ka re jare omo oduduwa tootoo
 
khafilat

Well-Known Member
#7
Iya Laje said:
Mayo mayo mayo o lori olumo
mayo mayo mayo o lori olumo
Ibe lo gbe bi mi si o
Ibe lo gbe to mi dagba o
mayo mayo mayo o lori olumo...............
E jo o, emi o mo oriki ile mi o, sugbon mo mo oriki temi, as in ti oruko mi, se mo le so iyen

Trust u.
 
vince

Well-Known Member
#9
My mama had this very beautifully poetic ekiti oriki that she always used to calm us down whenever we were upset back in our youth days.I am trying to remember now.I will pada wa if i remember anything. :)
 
Okestra007

Mr. Lover Man
#11
Oyinkan said:
Oya o, e yin te ba mo oriki ile yii n, oriki adugbo yii n, ati ti ilu yii n o, e wa ma so, e yii afi je ka mo awon omo naijarules to je omo oduduwa ijinle

Oriki Ibadan
Ibadan ile Oluyole,
Ibi t'ole ti n jare oni wun
Omo a fi ka raun fori mu
(e ma blame mi o, mi n sho mo Ibadan)

Oriki Oyo
Oyo a yo mo le sumtin, sumthin, sumthin
You should be on the phone with me whenever I call my grandma. She got all those thing down pack.
Jagbada, Onile yon rin, .......
She's good at it, and I get it everytime I call her.
 
khafilat

Well-Known Member
#12
vince said:
My mama had this very beautifully poetic ekiti oriki that she always used to calm us down whenever we were upset back in our youth days.I am trying to remember now.I will pada wa if i remember anything. :)
Arnt u fron OLUMO ROCK CITY any longer(just curious)
 
Aesha

Active Member
#14
omo olofa majo
omo abisu jookan
omo ijakadi lo'roo offa
omo ijakan tan ja nile olalomi
won se loju tani
ibase.....
sumthin' sumthin' sumthin'
 
Status
Not open for further replies.
Top