She Ki Ama So Ede Yoruba Nikan Ni Ibi Yi

vince

Well-Known Member
#21
Omo-Oko said:
Mo fowo si! Mo fese si!! Mo tun fi Ikebe mi si!!! Eyin Omo Oodua, e je ki a maa so Yoruba nikan nibi. Oya e je ki a wa oruko Yoruba fun "Naija Rules" ki a pee ni "Agbo Naija" ni www.agbonaija.com. Boya ka tie tun wa Yoruba fun "www" ati ".com" yen gan. Ki a maa pee ni:

www(world-wide web) = kaa(kolofin agbanla aye)
.com = .wa (se emo pe come=wa)

So, adiresi tuntun wa ree o:
kaa.agbonaija.wa
Ara e o ya o,omo-oko! :lol
 
Tajmahal

Well-Known Member
#23
Omo-Oko said:
Mo fowo si! Mo fese si!! Mo tun fi Ikebe mi si!!! Eyin Omo Oodua, e je ki a maa so Yoruba nikan nibi. Oya e je ki a wa oruko Yoruba fun "Naija Rules" ki a pee ni "Agbo Naija" ni www.agbonaija.com. Boya ka tie tun wa Yoruba fun "www" ati ".com" yen gan. Ki a maa pee ni:

www(world-wide web) = kaa(kolofin agbanla aye)
.com = .wa (se emo pe come=wa)

So, adiresi tuntun wa ree o: kaa.agbonaija.wa
O fi'kebe e si! Ah! Omode yi ti yanma oh! bgrin: Se omo pe ikebe e le fo "kolofin agbanla aye" ta n so yen sha?? :D Ewo ninu e ti e ni oruko e gan? Omo-Oko yen, a le tu si ona bii mefa oh! bgrin:

Awon gba ran mi t'odeleru gbogbo ti won sope kama so Yooba ni bi. Shebi 'Yoruba Movies" ni won pe ibi ti a wa yi? Abi beeko?? Nigba ti otije bee, e je ki a 'go on soun' jo!!

OlaAf, Fiinsi, Lafeeeeeeeeeeemu, MultiO, Hubs ore mi, ise de!!! Ehn! Gegebi alagba Finsi ti so, mi oro pe a maa gba 'Yooba ajebota' ni ibi bayi oh! Won bi wa s'Eko, a dagba s'Eko, sugbon Yooba Eko kii se ijinle rara, ta nni Yooba Brazil ati Sierra-Leone?? :laugh:
 
Omo-Oko

Active Member
#26
Tajmahal said:
O fi'kebe e si! Ah! Omode yi ti yanma oh! bgrin: Se omo pe ikebe e le fo "kolofin agbanla aye" ta n so yen sha?? :D Ewo ninu e ti e ni oruko e gan? Omo-Oko yen, a le tu si ona bii mefa oh! bgrin:

Awon gba ran mi t'odeleru gbogbo ti won sope kama so Yooba ni bi. Shebi 'Yoruba Movies" ni won pe ibi ti a wa yi? Abi beeko?? Nigba ti otije bee, e je ki a 'go on soun' jo!!

OlaAf, Fiinsi, Lafeeeeeeeeeeemu, MultiO, Hubs ore mi, ise de!!! Ehn! Gegebi alagba Finsi ti so, mi oro pe a maa gba 'Yooba ajebota' ni ibi bayi oh! Won bi wa s'Eko, a dagba s'Eko, sugbon Yooba Eko kii se ijinle rara, ta nni Yooba Brazil ati Sierra-Leone??
E gba mi o!!! Mo ti fe rerin ku o!!!! hahahahahehehe!!! Taju mahali lo fe pa mi o! Ikebe mi a fo kolofin agbanla aye...hahahahahehehehehahaha!!!! :lol

vince said:
Ara e o ya o,omo-oko! :lol
Finsi, o re iwo gan.
 
Tajmahal

Well-Known Member
#28
vince said:
Taju,o ti gbo yooba Cuba ri sha?Baba ijinle yooba,ti o clean buruku.
Yooba Cuba ke? Mo gbo ni gbakan ri sha. Won ni Yooba wan leku!!! Ore mi Fiinsi, fi surutu le jo!! Aa fe Yooba 'Diaspora' jare, ijinle la n fe. Ki ni'yato larin Cuba ati Brazil??
 
Tajmahal

Well-Known Member
#29
Omo-Oko said:
E gba mi o!!! Mo ti fe rerin ku o!!!! hahahahahehehe!!! Taju mahali lo fe pa mi o! Ikebe mi a fo kolofin agbanla aye...hahahahahehehehehahaha!!!! :lolFinsi, o re iwo gan.
Omo-O fun ra e! Ikun mi gan ti fee be fun erin ti mo n rin!! bgrin: Mo kan wo iru ikebe to le fo kolofin agbanla aye! Ojigbijigbi!!! :biggrinsa
 
vince

Well-Known Member
#32
Tajmahal said:
Yooba Cuba ke? Mo gbo ni gbakan ri sha. Won ni Yooba wan leku!!! Ore mi Fiinsi, fi surutu le jo!! Aa fe Yooba 'Diaspora' jare, ijinle la n fe. Ki ni'yato larin Cuba ati Brazil??
Yooba won ni Brazil ti baje,taju.Won ti po mo potogi,sugbon ni Cuba,yooba won da duro ni gedere!Ko si ede imi ninu re rara.
 
Tajmahal

Well-Known Member
#34
vince said:
Yooba won ni Brazil ti baje,taju.Won ti po mo potogi,sugbon ni Cuba,yooba won da duro ni gedere!Ko si ede imi ninu re rara.
Fiinsi, maa ni lati s'ewadi lori oro Cuba to n so yi o! To ba ri be, mo gbe'di fun won sha.............
 
vince

Well-Known Member
#37
Gen Sani Abacha said:
Lukumi ni won npe ede Yoruba ni orile-ede Kuba. Iran awon adulawo ti won je olorisa ni won nibeyen.
odigba
E se pupo,adupe o,olori orile ede naija atijo,ti o ti ku danu! :spiny:
 
Tajmahal

Well-Known Member
#38
vince said:
Ejo ki ni oruko arabirin funfun ti o wa l'ati ilu austria ti o 'n bo OSUN OSHOGBO?
Ann Suiner ( mi o ranti oruko keji yi daadaa) ni oriko e, sugbon Adunni Olorisha ni awon ara ilu Osogbo fun. Oruko naa ni gbogbo aye moo si...........
 
Gen Sani Abacha

Well-Known Member
#40
Tajmahal said:
Ann Suiner ( mi o ranti oruko keji yi daadaa) ni oriko e, sugbon Adunni Olorisha ni awon ara ilu Osogbo fun. Oruko naa ni gbogbo aye moo si...........
Iro o, Susan Wenger ni oruko e o!

Wo ibi bayi fun itan awon lukumi ti mo so yii :http://www.bembe.com/conjunto/

vince said:
E se pupo,adupe o,olori orile ede naija atijo,ti o ti ku danu! :spiny:
Mo wa jin nide nisinsinyii. Gba tie violent:

Tajmahal said:
Iyen ni wipe 'akudaaya' ni Ogagun Abasha Basha Basha ni ori eto Naija Ruulu.............
Iwo omo eniyan, iwo naa ni mo pada wa mu niso si ode orun. Oya kalo! :ringed
 
Top