1. This site uses cookies. By continuing to use this site, you are agreeing to our use of cookies. Learn More.

She Ki Ama So Ede Yoruba Nikan Ni Ibi Yi

Discussion in 'MOVIES IN AFRICAN LANGUAGES' started by vince, Jan 27, 2004.

 1. Dsampler

  Dsampler D. Ultimate Naija Ruler

  Joined:
  Jun 11, 2004
  Messages:
  7,175
  Likes Received:
  153
  Wot da hell is goin on here?
   
 2. vince

  vince Well-Known Member

  Joined:
  Oct 24, 2003
  Messages:
  25,208
  Likes Received:
  274
  El general,esu o si ni orun apaadi o!Owun at awon emewa re ti travel....
  Mo fe sere de orun,nitori pe mo gbo pe party kan nsele nibe.
  Wan ni awon angeli nse owambe party fun jesu,buddha ati orunmilla.Mo de gbo pe party yen ma gbona gidi gaaan ni.
  Se el general a te le mi lo?Ti o ba le ko awon omoge NR bi melo kan dani,ki a lo baraje ni be jati jati.
  Ni asiko yi,orun apaadi dry bi thread yi,so....sweat::spin2:
   
 3. vince

  vince Well-Known Member

  Joined:
  Oct 24, 2003
  Messages:
  25,208
  Likes Received:
  274
  Mi o gbeebo.
   
 4. Gen Sani Abacha

  Gen Sani Abacha SUPREME DICTATOR

  Joined:
  Jan 12, 2004
  Messages:
  8,330
  Likes Received:
  71
  Ede Yoruba nikan ni a nmulo ni awujo yi o! (This thread is strictly a Yoruba language medium oh!).
   
 5. Gen Sani Abacha

  Gen Sani Abacha SUPREME DICTATOR

  Joined:
  Jan 12, 2004
  Messages:
  8,330
  Likes Received:
  71
  Alaye mi Vinsoma, emi ati e ko o!
  Maa jegbadun re lo layo ati alafia...smokin:
   
 6. kolinzo

  kolinzo Oodua4life

  Joined:
  Apr 8, 2004
  Messages:
  7,000
  Likes Received:
  167
  Oluwaa mi, iru ede wo ni olofofo n'so yi? E dakun, se yooba ti Benin Republic ni, abi eyi ti won n'so ni Togo?

  B'o ba se je sa, eyin eyan mi, e ma gbadun lo!
   
 7. vince

  vince Well-Known Member

  Joined:
  Oct 24, 2003
  Messages:
  25,208
  Likes Received:
  274
  Mo ti pinu pe mi o ni so ede geesi ni inu forum yi mo,lai ati lai lai!Mo le ma so yoobanglish o,sugbon ko si aye fun ede geesi lasan mo.
  Mo fe ma se akosile ni ede abinibi ni igba gbogbo, lati eni lo.
  Ni ati ijo ti wan ti bi mi,ti wan ba ni ki wan ko gbogbo akosile ni ede yoruba ti mo ti ko titi di ojo oni jo,mi o ro pe o le kun paper kan!
  ITIJU GBAAAA! :thumbs_down:
  Ejo mi si ko!Ni igba ti wan ba komi ni ede abinibi ni ile iwe.
  Sugbon ko i ti pe ju.O ba ni,ko baje.Kiko si ni mimo.Atunse bere ni ati oni yi lo,ni orile ede NR Rebublic!
  Mo si ti bere si ma ko script ni ede yooba,o si n'dun mo mi gidi gaaani!grinning:

  Eni ti o ba dun mo,ki o lo be s'odo!smokin:
   
 8. peculiar

  peculiar Well-Known Member

  Joined:
  Jan 15, 2004
  Messages:
  14,042
  Likes Received:
  147
  Ko dun mo mi o, alagba Finsi! Sugbon ko si odo kankan ni adugbo ti mo n gbe!sweat:sweat:
   
 9. Gen Sani Abacha

  Gen Sani Abacha SUPREME DICTATOR

  Joined:
  Jan 12, 2004
  Messages:
  8,330
  Likes Received:
  71
  Iyen ni pe awon enyan si maa nde ibi bayi sa ?
  Mo ti lero wipe...................hmmmmmmmmmm
   
 10. vince

  vince Well-Known Member

  Joined:
  Oct 24, 2003
  Messages:
  25,208
  Likes Received:
  274
  O ma se o!:)
   
 11. vince

  vince Well-Known Member

  Joined:
  Oct 24, 2003
  Messages:
  25,208
  Likes Received:
  274
  Oloogbe abasha,ewo lo se?Se orun n'dun?
   
 12. Gen Sani Abacha

  Gen Sani Abacha SUPREME DICTATOR

  Joined:
  Jan 12, 2004
  Messages:
  8,330
  Likes Received:
  71
  Ogbeni Fiinsi, kilonsele ?
   
 13. vince

  vince Well-Known Member

  Joined:
  Oct 24, 2003
  Messages:
  25,208
  Likes Received:
  274
  Oloogbe Abasha!O ku atijo!O ti ji nde ko nu?:food-smil
   
 14. Abike

  Abike Well-Known Member

  Joined:
  Jun 28, 2004
  Messages:
  15,841
  Likes Received:
  224
  Buroda Finsi!!!!

  Ki'ode??? Se o si??? A ri oju yin ni le.....mo ni n ki yin ni o..... :fing33:
   
 15. beautiful

  beautiful Member

  Joined:
  Jan 28, 2008
  Messages:
  36
  Likes Received:
  1
  i can see dat dis thread is meant for people dat have too much oil in there soup
   
 16. Gen Sani Abacha

  Gen Sani Abacha SUPREME DICTATOR

  Joined:
  Jan 12, 2004
  Messages:
  8,330
  Likes Received:
  71
  Alaye mi Finsoma. Iye ainipekun ni Olorun fi fun mi o! :music-smi
   
 17. paj

  paj D JENGBORAN OF YORUBALAND

  Joined:
  Jan 15, 2005
  Messages:
  22,960
  Likes Received:
  141
  ..Egbon Sola,e joo..e ba mi moderate oku'ugbe yi lo si ile iso...E seun...smokin:
   
 18. paj

  paj D JENGBORAN OF YORUBALAND

  Joined:
  Jan 15, 2005
  Messages:
  22,960
  Likes Received:
  141
  :shock
   
 19. paj

  paj D JENGBORAN OF YORUBALAND

  Joined:
  Jan 15, 2005
  Messages:
  22,960
  Likes Received:
  141
  ....IBO NI ERASER KINI YI WA NOW???:gnash:grin
   
 20. saymamy

  saymamy Active Member

  Joined:
  May 8, 2007
  Messages:
  147
  Likes Received:
  2
  lol.....o funny gaaaan ni. Ma se ti e lo jare....
   

Share This Page