1. This site uses cookies. By continuing to use this site, you are agreeing to our use of cookies. Learn More.

She Ki Ama So Ede Yoruba Nikan Ni Ibi Yi

Discussion in 'MOVIES IN AFRICAN LANGUAGES' started by vince, Jan 27, 2004.

 1. peculiar

  peculiar Well-Known Member

  Joined:
  Jan 15, 2004
  Messages:
  14,042
  Likes Received:
  147
  Daadaa la wa o, ogbeni Abacha. E ku iwoyi o... ;) se gbogbo nkan n lo deedee?
   
 2. Gen Sani Abacha

  Gen Sani Abacha SUPREME DICTATOR

  Joined:
  Jan 12, 2004
  Messages:
  8,330
  Likes Received:
  71
  Sisi mi Pekuliariti, omoge pelenge, adulewa ope ni fun Oloun o, Amin, Jesu...:)
   
 3. peculiar

  peculiar Well-Known Member

  Joined:
  Jan 15, 2004
  Messages:
  14,042
  Likes Received:
  147
  Hmm....alagba Sani, shey eebu ni "pelenge" yin yen, abi esa??? corkysm60:
   
 4. Gen Sani Abacha

  Gen Sani Abacha SUPREME DICTATOR

  Joined:
  Jan 12, 2004
  Messages:
  8,330
  Likes Received:
  71
  Omidan Pekuliar, eetiri ? eebu bi ti bawo ? :frown2
  Mo nsa e ni o, faaini geeli lukin segzy ni mo fe so o...;)
   
 5. peculiar

  peculiar Well-Known Member

  Joined:
  Jan 15, 2004
  Messages:
  14,042
  Likes Received:
  147
  O da, mo gba yin gbo!:fing02:

  Ere yoruba de n wu mi i wo sha. :redface Sugbon oorun ti n kun mi, ise de wa ni aaro ola. help:

  O dabi wipe, emi n lo sun niyen o. O daaro o, eyin ara mi lori NR. Ipade wa bi oyin o...okookan la o ji o! Amin. :fing33:
   
 6. Gen Sani Abacha

  Gen Sani Abacha SUPREME DICTATOR

  Joined:
  Jan 12, 2004
  Messages:
  8,330
  Likes Received:
  71
  O daaro o aburo mi owon, ka sun layo, ka ji layo o, Amin.

  Ebi dee ti e npa mi sa....huuuuuuuuuun, maa lo wa nkan je ki nto sun.

  Eyin ara NR, mo ri yin naa...:)
   
 7. paj

  paj D JENGBORAN OF YORUBALAND

  Joined:
  Jan 15, 2005
  Messages:
  22,960
  Likes Received:
  141
  ...ah ha..wah na O..Generah...kii she Gambari ni e ni?:gnash bai di we(by the way :D),share mi ninu owo ti o ko je ni igba Ijoba re da?:knuck
  Pa
   
 8. SoulfulAngel

  SoulfulAngel Active Member

  Joined:
  Apr 11, 2010
  Messages:
  311
  Likes Received:
  18
  Kilo n sele now...Ibi bayi ti gbe sha...
  :angel
   
 9. Gen Sani Abacha

  Gen Sani Abacha SUPREME DICTATOR

  Joined:
  Jan 12, 2004
  Messages:
  8,330
  Likes Received:
  71
  Eyin ara abuleeeeeeeeee da ???
   
 10. vince

  vince Well-Known Member

  Joined:
  Oct 24, 2003
  Messages:
  25,208
  Likes Received:
  274
  A si nle o! A ti lo roko oba! Te ba fe kan wa lara, e pe wa sori ago owo. E seun.:spin2:
   
 11. Gen Sani Abacha

  Gen Sani Abacha SUPREME DICTATOR

  Joined:
  Jan 12, 2004
  Messages:
  8,330
  Likes Received:
  71
  Ti o ba fe gba sia tire, lo ba onku Sege alias baba Iyabo soro, owo re ni gbogbo owo naa wa bayii ooooooooo.
   
 12. Gen Sani Abacha

  Gen Sani Abacha SUPREME DICTATOR

  Joined:
  Jan 12, 2004
  Messages:
  8,330
  Likes Received:
  71
  Aaaa kan sin yin laipe yii, E maa wole, e maa rora o,
   
 13. vince

  vince Well-Known Member

  Joined:
  Oct 24, 2003
  Messages:
  25,208
  Likes Received:
  274
  E kaaro, e jiire o, gbogbo eyin omo oodua! Mo ki gbogbo gbo! Mo juba, kiba se! :fam14:
   
 14. vince

  vince Well-Known Member

  Joined:
  Oct 24, 2003
  Messages:
  25,208
  Likes Received:
  274
  E seun. Owo a ma roke o!
   
 15. Gen Sani Abacha

  Gen Sani Abacha SUPREME DICTATOR

  Joined:
  Jan 12, 2004
  Messages:
  8,330
  Likes Received:
  71
  Ati tire naaa o, Amin Jesu Oba ogo....:)
   
 16. Abike

  Abike Well-Known Member

  Joined:
  Jun 28, 2004
  Messages:
  15,841
  Likes Received:
  224
  GSA!!! O to jo meta o!
   
 17. Gen Sani Abacha

  Gen Sani Abacha SUPREME DICTATOR

  Joined:
  Jan 12, 2004
  Messages:
  8,330
  Likes Received:
  71
  Sisi mi Abike, ojo kan pelu o. Se daadaa ni ? Awon ara ile nko ?
   
 18. msjollies

  msjollies Planner Extraodinaire

  Joined:
  Mar 30, 2005
  Messages:
  1,520
  Likes Received:
  4
  awon temi, se gbo yin wa? se gbo gbo e mellow? ekaro o eni ada fun gbogbo wa o!
   
 19. vince

  vince Well-Known Member

  Joined:
  Oct 24, 2003
  Messages:
  25,208
  Likes Received:
  274
  Ojo iku lojo isinmi.
  Nkan to ba wu onikaluku ni ko fi ori ara re se.
  E je ki onikaluku sogba e.
  Oto oro, omo iya isokuso ni o.
  Inu rere o se fowo ra.

  Eyin eyan, e ni lo si orile ede ti wan npe ni "Talikania" fun greener pastures o. Ase!

  O tun digba!
   
 20. Gen Sani Abacha

  Gen Sani Abacha SUPREME DICTATOR

  Joined:
  Jan 12, 2004
  Messages:
  8,330
  Likes Received:
  71
  E ku Sonde ojo-isinmi nibi yi o...
   

Share This Page