She Ki Ama So Ede Yoruba Nikan Ni Ibi Yi

#41
O ga ju! E ma se wa lese o. Erin subu lan rin ni bi!
Ogagun to ji dide lati orun titi lailai, jowo saanu o. Ma mu eniyan kankan dani o.
Ori ikunle ni a wa. An gbadun bi won sen dawa lara ya! :D
 
Gen Sani Abacha

Well-Known Member
#42
funmo said:
O ga ju! E ma se wa lese o. Erin subu lan rin ni bi!
Ogagun to ji dide lati orun titi lailai, jowo saanu o. Ma mu eniyan kankan dani o.
Ori ikunle ni a wa. An gbadun bi won sen dawa lara ya! :D
Iwo omo eniyan, ti o ko ba fe ki a mu eda kankan lo si ode orun, wa sanwo isakole ni o! Wole o bode, ja mi ni taitu, fain bara joo! :mad:
 
Gen Sani Abacha

Well-Known Member
#43
Omo-Oko said:
Mo fowo si! Mo fese si!! Mo tun fi Ikebe mi si!!! Eyin Omo Oodua, e je ki a maa so Yoruba nikan nibi. Oya e je ki a wa oruko Yoruba fun "Naija Rules" ki a pee ni "Agbo Naija" ni www.agbonaija.com. Boya ka tie tun wa Yoruba fun "www" ati ".com" yen gan. Ki a maa pee ni:

www(world-wide web) = kaa(kolofin agbanla aye)
.com = .wa (se emo pe come=wa)

So, adiresi tuntun wa ree o: kaa.agbonaija.wa
Omo-oko, aya mi atata, wa so mo mi, wa fi ikebe re da mi lara ya o! :yellow:
 
#45
Gen Sani Abacha said:
Iwo omo eniyan, ti o ko ba fe ki a mu eda kankan lo si ode orun, wa sanwo isakole ni o! Wole o bode, ja mi ni taitu, fain bara joo! :mad:

'419' ni awon eleyinbo pe iyen o! Iwa yii gan, o le ju ti Abacha lo ki o to ku o!
O ga o!
 
Tajmahal

Well-Known Member
#47
Gen Sani Abacha said:
Iro o, Susan Wenger ni oruko e o!

Iwo omo eniyan, iwo naa ni mo pada wa mu niso si ode orun. Oya kalo! :ringed
Ogagun Abasha Basha Basha, ni igba akoko ri, o so otito. Oruko elomi ni mo lo pe.

"Iwo akudaaya Ogagun, awon omo ilu India ti o fun loyun (ni ipase eso oyinbo ta n pe ni apulu - apple) nigba aye e ni Naija, awon ara Kano ti le won lo o! Won ni omo ale ni won". :biggrinsa
 
Tajmahal

Well-Known Member
#48
funmo said:
'419' ni awon eleyinbo pe iyen o! Iwa yii gan, o le ju ti Abacha lo ki o to ku o!
O ga o!
Funmo, rora se l'odo Ogagun Abasha Basha Basha o! Ranti awon omo ilu India pelu eso apuulu (apple). Gbogbo owo to ji ni Naija shi wa ni ile ifowopamo o! Eleyi ji '419' lo o! Agbalagba jibiti leyi o............
 
Tajmahal

Well-Known Member
#51
Gen Sani Abacha said:
Omo-oko, aya mi atata, wa so mo mi, wa fi ikebe re da mi lara ya o! :yellow:
Ogagun Abasha, 'a n gb'omo adie e lowo iku, o ni ao je ki ohun lo si akitan lo je'. Bi oshe fi orishirishi ikebe dara e l'araya ni yen ni orile ede Naija nigba ti o je olori, ti o fi di ara saare lojiji. O fi Ayaba re, Mariamo, bi oti pupa roboto to, sile ni Kano ati Abuja, o n f'owora ikebe kaakiri agbaye!! Haba Omo Adamo, oro ti ikebe maa dale, agbara ikebe ko nii le ka rara rara!!! :D
 
Gen Sani Abacha

Well-Known Member
#53
Tajmahal said:

Iwo Taju omo Mahali yi, ma je ki n ran Shina Rambo wa ka e mole o, sebi o mo wipe Kutonu lo sapa mo si ? Ma a se e ni Basha Basha bi oruko ti o fi pe mi! Nonba Moriamo ko wole mo jare ("old Cargo" lo n je bee), eja tutu la wa nta si bayii o! Ti omo India o ba see fe mo, maa fori si odo awon omo Saini. :bouncy
 
#56
Gen Sani Abacha said:
Ati 4-1-9 o, ati 4-1-10 o, ko si eyi ti o kan mi nibe, ti o ko ba fe ki n ti e mo orun apaadi, tete lo san owo ori o! smokin:

Oda o, o da bi eni pe ire ko mo wipe kosi eni ti ole gba owo lowo eni keni ni ibi yi, lai jepe Baba (Area fada) mo si. Owo won ni gbogbo owo wa. Ogagun basha (mo gba ti oruko yen sha!), lo sofun Area fada pe mo jee lowo.
Sofun mi ni nkan ti won ba so.
:nature-sm
 
Tajmahal

Well-Known Member
#57
vince said:
Ogagun orile ede nigeria atijo,ti o ti padanu emi re ni owo awon ashewo ti won wa lati mecca,e seun pupo fun linki itakun yen!E seun,mo dupe.
Lori ona(by the way),se Susan Wenger yi tan mo Arsene Wenger?Ibere ni o!E seun.
Fiinsi, akoni sita bi omo ojomejo! Ta n so fun e pe Mecca ni awon ashewo to gbemi Ogagun Abasha ti wa?? Oti o! Ilu India ni o!

Gegebi oluferan egbe Arsenal tooto, mo n fi asiko yi so fun e wipe koosi (coach) wa, Arsene Wenger, ko tan mon Susan Wenger rara. Omo orile ede Faranse (France) ni koosi (coach), atipe omo orile ede Jamani (Germany) ni Adunni Olorisha, Susan!
 
Tajmahal

Well-Known Member
#58
Gen Sani Abacha said:
Iwo Taju omo Mahali yi, ma je ki n ran Shina Rambo wa ka e mole o, sebi o mo wipe Kutonu lo sapa mo si ? Ma a se e ni Basha Basha bi oruko ti o fi pe mi! Nonba Moriamo ko wole mo jare ("old Cargo" lo n je bee), eja tutu la wa nta si bayii o! Ti omo India o ba see fe mo, maa fori si odo awon omo Saini. :bouncy
Ogagun Abasha, o ga fun e o!! Nigba ti o gbo Moriamo jigijigi tan, to bi omo mewa (ishe n la lo se Ogagun) jo fun e tan, owa n pe ni eleje gbigbona. Shaa rora, eje tutu n paa yan!

Awi tai wi, o ni omo Saini lo tun kan!!! Oluwa aa gba e sha!!

E je ki n so Ibadan die: Sina Rambo, ni Kutonu l'enkunle wa n be un! Sio, sio, iranu lasan, lasan! Boya lo ma pe ajesara n be; ajesikun tun wa pelu. Omode o moogun, in pe lefo. Ta n n'iranu! Baami Adedibu n be n'badan!
 
Hubscrown

Well-Known Member
#59
Olomoku'in Taju, sei sepe omo 'Badan ni o? Ede enu re jo tawon omo 'badan. Laisarojiyan, Oga elere 'daraya na mon npe "Koshi". Fiinsi, 'By the way' iise Loju ona, lol (Erin nla) :laugh: . O le sope pelupelu tabi laise aniani.

Tajmahal said:
Fiinsi, akoni sita bi omo ojomejo! Ta n so fun e pe Mecca ni awon ashewo to gbemi Ogagun Abasha ti wa?? Oti o! Ilu India ni o!

Gegebi oluferan egbe Arsenal tooto, mo n fi asiko yi so fun e wipe koosi (coach) wa, Arsene Wenger, ko tan mon Susan Wenger rara. Omo orile ede Faranse (France) ni koosi (coach), atipe omo orile ede Jamani (Germany) ni Adunni Olorisha, Susan!
 
Tajmahal

Well-Known Member
#60
funmo said:
Oda o, o da bi eni pe ire ko mo wipe kosi eni ti ole gba owo lowo eni keni ni ibi yi, lai jepe Baba (Area fada) mo si. Owo won ni gbogbo owo wa. Ogagun basha (mo gba ti oruko yen sha!), lo sofun Area fada pe mo jee lowo.
Sofun mi ni nkan ti won ba so.
:nature-sm
Funmo, oo ti mo Ogagun Abasha to n ba sh'awada yi o! Oro pe owo lasan ni taitu to nso ni! Leyin owo, waa tun na ara pelu!!! :laugh:
 
Top