She Ki Ama So Ede Yoruba Nikan Ni Ibi Yi

Hubscrown

Well-Known Member
#61
Tajmahal said:
Ogagun Abasha, o ga fun e o!! Nigba ti o gbo Moriamo jigijigi tan, to bi omo mewa (ishe n la lo se Ogagun) jo fun e tan, owa n pe ni eleje gbigbona. Shaa rora, eje tutu n paa yan!

Awi tai wi, o ni omo Saini lo tun kan!!! Oluwa aa gba e sha!!

E je ki n so Ibadan die: Sina Rambo, ni Kutonu l'enkunle wa n be un! Sio, sio, iranu lasan, lasan! Boya lo ma pe ajesara n be; ajesikun tun wa pelu. Omode o moogun, in pe lefo. Ta n n'iranu! Baami Adedibu n be n'badan!
Mo so be na, pe ede enu re jo tawon ara 'badan. So'mo badan ni o' ni abi o' njede lo? :rolleyes:
 
Omo-Oko

Active Member
#62
Gen Sani Abacha said:
Omo-oko, aya mi atata, wa so mo mi, wa fi ikebe re da mi lara ya o! :yellow:
hahahaha!!! Mi o tie ri eleyi tele sha! Ogagun Abasha, Asewo India lo pe mi ni? O je tete ni ki awon Mustapha ati Roger lo fi baalu ko awon Asewo re wa lati India. Dakun see mi sa ojee!!! Enranu! :glasses
 
#63
Omo-Oko said:

Ore mi atata, mo wa lehin e bi ike ojare.
Sofun ki o gbo! :action-sm
 
Hubscrown

Well-Known Member
#65
Gen Sani Abacha said:
Ara ni mo maa pe ranse si gbogbo yin! :guns
Sanni, O' mo' wipe awon ti won le mu ara mbe. Epo pupa lero' ara, eni bati lepo pupa nle, o m'ara. Nwo ba o' wi, Sebi ajeji nio' nile' yooba. Ta nko' o' lede gann??
 
#66
Tajmahal said:
Swit sokoleeti, kaabo si ori eto yi, fun wa ni 'logo' e! Iyen la n ba e so, abi ki o ja wa ni efe tabi ijinle Yooba ni bi........... :laugh:

lol tajimahali..ese gan ni ..logo iru ewo len so.....gbogbo NR oti ready fun yoruba mi :imp
 
Tajmahal

Well-Known Member
#70
Hubscrown said:
Olomoku'in Taju, sei sepe omo 'Badan ni o? Ede enu re jo tawon omo 'badan. Laisarojiyan, Oga elere 'daraya na mon npe "Koshi". Fiinsi, 'By the way' iise Loju ona, lol (Erin nla) :laugh: . O le sope pelupelu tabi laise aniani.
Ore mi Obusikraun, :laugh: mi n se omo'badan rara o; mi o ti e tan mo won. Sugbon mo gba ti ede yen. To ba fee feran Ibadan ni siso, ki o wo fiimu ti arabinrin Binta Ayo Mogaji ba ti so ede naa, nishe ni waa maa gbadun e!
 
Tajmahal

Well-Known Member
#72
Omo-Oko said:
hahahaha!!! Mi o tie ri eleyi tele sha! Ogagun Abasha, Asewo India lo pe mi ni? O je tete ni ki awon Mustapha ati Roger lo fi baalu ko awon Asewo re wa lati India. Dakun see mi sa ojee!!! Enranu! :glasses
Omo-Oko, ah, yoo da fun o pelu ede to fo n'beun! See n mi sa ojee (Ibadan ijinle). Yoo ye o! :)
 
Tajmahal

Well-Known Member
#73
Sweetchocolate said:
lol tajimahali..ese gan ni ..logo iru ewo len so.....gbogbo NR oti ready fun yoruba mi :imp
Sokoleeti, o se gan ni fun idahun e :laugh: .............sugbon mo n reti Yooba e ni kiakia. Gegebi a ti so lati'bere, a o fe Yooba Brazil, Cuba, Kutonu (Cotonou), Sierra-Leone, ati bee bee lo..........ijinle la n fe!
 
vince

Well-Known Member
#74
Fiinsi, akoni sita bi omo ojomejo! Ta n so fun e pe Mecca ni awon ashewo to gbemi Ogagun Abasha ti wa?? Oti o! Ilu India ni o!
O seun fun laakaye re,taju omo mahali.Sugbon,mo ni ibeere miran.Se awon ashewo india won yen,jo ijo bollywood,ki won to gba emi ogagun Abasha,ti won si ran lo si orun apadi?
E se pupo,e se adupe o!
 
vince

Well-Known Member
#75
Sweetchocolate said:
lol tajimahali..ese gan ni ..logo iru ewo len so.....gbogbo NR oti ready fun yoruba mi :imp
Eee oo!Sokoleti,sokonimu na ma'n so yooba ke!Inu mi si dun pupo! :D :action-sm grinning:
 
vince

Well-Known Member
#76
E ku odun titun o!

Mo ni ki'n ki gbogbo awon omo Oduduwa ku odun titun,ku iyedu o!
Odun yi ayabo o!
Odun yi a mirigidi!
Adupe pe awa o pelu awon ti won ba odun esi lo o!Ope ni fun eledumare,oba ti'n d'abo bo awon omo re!Ogo ni fun olodumare!
E pe nu iya o!(happy new year)
 
Sweetchocolate

Well-Known Member
#80
Tajmahal said:
Sokoleeti, o se gan ni fun idahun e :laugh: .............sugbon mo n reti Yooba e ni kiakia. Gegebi a ti so lati'bere, a o fe Yooba Brazil, Cuba, Kutonu (Cotonou), Sierra-Leone, ati bee bee lo..........ijinle la n fe!
lol..emi ati yoruba ijinle mi n bo...esa ma ready fun :biggrinsa
 
Top