1. This site uses cookies. By continuing to use this site, you are agreeing to our use of cookies. Learn More.

She Ki Ama So Ede Yoruba Nikan Ni Ibi Yi

Discussion in 'MOVIES IN AFRICAN LANGUAGES' started by vince, Jan 27, 2004.

 1. Sweetchocolate

  Sweetchocolate Omonaija tio gba gbere

  Joined:
  Dec 1, 2003
  Messages:
  2,807
  Likes Received:
  1

  lol..sokoleti le so yoruba o :D
   
 2. robeta_021

  robeta_021 Well-Known Member

  Joined:
  Mar 4, 2004
  Messages:
  4,313
  Likes Received:
  3
  hmmm...okay, make I comot myself quick quick.
   
 3. Gen Sani Abacha

  Gen Sani Abacha SUPREME DICTATOR

  Joined:
  Jan 12, 2004
  Messages:
  8,330
  Likes Received:
  71
  Fiinsi mein ubermoderator ni yio saaju lo si orun apaadi. Toun ti Itila ati Gobuusi ni won jo maa jerora ina oun! :guns
   
 4. Tajmahal

  Tajmahal Well-Known Member

  Joined:
  Nov 27, 2003
  Messages:
  1,503
  Likes Received:
  0
  Won fe jo ijo boliwuudu (bollywood) pa ni! Ni she ni wo n redi bi okoto!!! Won gbo Ogagun Abasha jigijigi tan, won si ran lo si orun aremabo...........(emi o mo boya apaadi ni o!!). :laugh: She mo ti dahun ibeere yen, Omowe Fiinsi.
   
 5. Tajmahal

  Tajmahal Well-Known Member

  Joined:
  Nov 27, 2003
  Messages:
  1,503
  Likes Received:
  0
  Bollyd, iwo gan ni o siriosi o! She o ti fo gbogbo awon abo ati awo ti a fi jeun ni ojo odun tan ni! Oya, kiakia, ki o wo kishin (kitchen) lo, ki o lo fo won. Ole omo (lazy child). :D
   
 6. Tajmahal

  Tajmahal Well-Known Member

  Joined:
  Nov 27, 2003
  Messages:
  1,503
  Likes Received:
  0
  Fiinsi, o she gan ni o. Mo she amin si adura yen gidigidi. :action-sm
   
 7. Tajmahal

  Tajmahal Well-Known Member

  Joined:
  Nov 27, 2003
  Messages:
  1,503
  Likes Received:
  0
  OlaAf, erin pa mi fun idahun e yi o! Kilode to n yo ara e kuro? Won ni gbogbo yin e siriosi, owa n so wipe gbogbo won?? She oo mo wipe iwo na wa ninu awon ti Bollyd so pe won siriosi ni?? bgrin: Ma je ki n binu o!! :laugh:
   
 8. Tajmahal

  Tajmahal Well-Known Member

  Joined:
  Nov 27, 2003
  Messages:
  1,503
  Likes Received:
  0
  Sokoleeti, odun melo la maa fi duro ki a to mo pe ole so Yooba ijinle daada? Ba mi pari owe yi: "Ireti pipe ma n ............"! :D
   
 9. Tajmahal

  Tajmahal Well-Known Member

  Joined:
  Nov 27, 2003
  Messages:
  1,503
  Likes Received:
  0
  Talo pe Robeta si ibi yi?? Afara, kia , modi oju mi, ti n ba laju ti mo ri e, maa ti lo na e ju!!!
   
 10. olaafol

  olaafol Well-Known Member

  Joined:
  Jul 10, 2004
  Messages:
  4,337
  Likes Received:
  2
  Tajmahal eniyan mi pataki, se alafia ni o wa bi emi na se wa ni ibiyi? Eku odun titun yi o; a san wa s'owo, s'omo, s'alafia, ati emi gigun - amin.

  Si ibere re e nipa Bollyd, Yooba ni mo lo fun yen - mo fe ki ofi enu ara re so awon ti o n ba wi ni ojare.
   
 11. olaafol

  olaafol Well-Known Member

  Joined:
  Jul 10, 2004
  Messages:
  4,337
  Likes Received:
  2
  TajM, mo ro wipe Yooba ni a fe ma so ni ibiyi, ewo wa ni eebo ti o nfi kun oro re?
   
 12. Gen Sani Abacha

  Gen Sani Abacha SUPREME DICTATOR

  Joined:
  Jan 12, 2004
  Messages:
  8,330
  Likes Received:
  71
  Jagunmolu Abasha ko se pa, ko se na loogun, woro woro lo n yan! music-sm:
  Ati Indiani, ati Saini ati Oyinbo, ati Yooba, gbogbo won ni won nku fun mi, emi naa si fun won ni nnkan ti won fe. Ajesara wa, ko si ewu legberun eko afi aidun obe. :laugh:
   
 13. Tajmahal

  Tajmahal Well-Known Member

  Joined:
  Nov 27, 2003
  Messages:
  1,503
  Likes Received:
  0
  OlaAf, omo Oodua tokan tokan, mo se amin meje si adura gbankogbi too she yen o!

  Uhn! Be n ti e ri! Oto ni ka bi ni ile Yooba, oto ki ashe af'ojuran (at'ojubo) gbo Yooba, oto ni ka ko ijinle Yooba fun ara e ni. O ku laakaye, Oluwa yio ke o jare! Oya Bollyd (egbo na, oruko yen she waa jo Bollywuudu bayi), fi esi si oro yi.
   
 14. Tajmahal

  Tajmahal Well-Known Member

  Joined:
  Nov 27, 2003
  Messages:
  1,503
  Likes Received:
  0
  OlaAf, oye koo jeri mi! She o mo wipe awon oni Yooba Brazil, Sierra-Leone, Peru, Kutonu ati bee bee lo wa ni ibi yi. Won le ma tete riipe kishini l'onje kitchen.............Mi o fe ki enikeni ka eyin ookan nitori wipe o fe pe oro Yooba. :)
   
 15. Tajmahal

  Tajmahal Well-Known Member

  Joined:
  Nov 27, 2003
  Messages:
  1,503
  Likes Received:
  0
  Eemo lukutupebe! Ta n fi Ogagun Abasha je oye Jagunmolu?? Se bi Rogers ati Mustapha she n paa yan kaakiri la fi n mo Jagunmolu ni??

  Ajesara, abi kinni?? Gbetugbetu ni, afoshe nko? Erin re n pami, ati iwo ati awon ti won ku fun o! Owo too koje ni Naija ni won ku fun, kii she ila Kanuri ti o wa leke ree ni won ku fun o!!!
   
 16. Gen Sani Abacha

  Gen Sani Abacha SUPREME DICTATOR

  Joined:
  Jan 12, 2004
  Messages:
  8,330
  Likes Received:
  71
  Owo ti mo koje ? Ajemonu ni'gun njebo! Awa Beriberi(Kanuri) naa la maa mu eyin Yoruba leru titi laelae. Ko si nnkan ti omo Yoruba le se fun wa. Gbogbo omoge lo feran owo, iyen o ki nse nnkan tuntun. Fadeyi oloro ni mo maa ran si e nisinyi! :sport-smi
   
 17. tombabe

  tombabe Active Member

  Joined:
  Nov 30, 2004
  Messages:
  154
  Likes Received:
  1
  don't do dat

  wat about people dat cannot read the language very well like me
   
 18. vince

  vince Well-Known Member

  Joined:
  Oct 24, 2003
  Messages:
  25,208
  Likes Received:
  274
  A o ti won mo atimole,beeni mo so!Ko si aye fun aimo ede abinibi wa.
  Se omo yooba n'iwo?Ti oba jebee,a o ti o m'ole,a si so kokoro atimole nu s'inu okun.Beeni mo wi! :imp
   
 19. vince

  vince Well-Known Member

  Joined:
  Oct 24, 2003
  Messages:
  25,208
  Likes Received:
  274
  Ose pupo,taju,o se modupe.
  O kan s'emi laanu ni,pe ko si awon ayaworan n'ibe pelu ero ayaworan,ni igba ti isele owun n'sele.
  Oye ki gbogbo aye ri bi ogagun abasha se ku iku esin.O ma se o!Shioo! :excite
   
 20. robeta_021

  robeta_021 Well-Known Member

  Joined:
  Mar 4, 2004
  Messages:
  4,313
  Likes Received:
  3

  Hmmm...Oga Tajmahal, abeg I no understand...
   

Share This Page