She Ki Ama So Ede Yoruba Nikan Ni Ibi Yi

D

Dessy

Guest
vince said:
Ose pupo,taju,o se modupe.
O kan s'emi laanu ni,pe ko si awon ayaworan n'ibe pelu ero ayaworan,ni igba ti isele owun n'sele.
Oye ki gbogbo aye ri bi ogagun abasha se ku iku esin.O ma se o!Shioo! :excite
lmao rotfl :laugh: :laugh:
 
D

Dessy

Guest
vince said:
Dessy mi!Wa pe nu'ya o(happy new year)!Bawo de ni?Se gbogbo e ndun?
Eledua o ma ni je ki emi pe ninu iya o. Opolopo igbadun ati ilera ara ni mo ma fi se odun yi jale o...Amin. Se alaafia ni e wa gege bi emi na ti wa nihin? E ku odun, e ku iyedu a se yi samodun o. Iwoyi emi, omo titun ati ile titun laa wa baa yin ko o.
 
Omo-Oko

Active Member
vince said:
Ema wo awon omokomo yi ti won so ede geesi ni ibi bayi!Abi iru palapala wo ni eyi ke? :screama:
E dakun jare, e ma binu. Omo robeta ajebutter yi ni ko le so Yoruba o! Mo wa so pe ki o san owo die fun mi ki n ba se itumo lo ba fariga o! O tun n na oja ni NR. :indif
 
D

Dessy

Guest
Omo-Oko said:

lol... :laugh:
 
vince

Well-Known Member

Ma ma da loun o!Ibi yi wa je ile eko bi?Owu?!Eese?!
 
vince

Well-Known Member
Dessy said:
Eledua o ma ni je ki emi pe ninu iya o. Opolopo igbadun ati ilera ara ni mo ma fi se odun yi jale o...Amin. Se alaafia ni e wa gege bi emi na ti wa nihin? E ku odun, e ku iyedu a se yi samodun o. Iwoyi emi, omo titun ati ile titun laa wa baa yin ko o.
Dessy mi,adura wa ti gba!A o ni r'ija Tsunami ni odun yi o!Amin!
 
Tajmahal

Well-Known Member
vince said:
Ose pupo,taju,o se modupe.
O kan s'emi laanu ni,pe ko si awon ayaworan n'ibe pelu ero ayaworan,ni igba ti isele owun n'sele.
Oye ki gbogbo aye ri bi ogagun abasha se ku iku esin.O ma se o!Shioo! :excite
Haba! Esin yen aa ti poju ke!!! She o ranti wipe Ogagun Abasha fi 'fiimu' awon Ogagun Diya, Adisa, Olanrewaju, ati awon 'odaran' to ku han gbogbo aye latari 'kuupu' ti Abasha so pe oshele ni odun yen? Beeni a o ba wo 'fiimu' Abasha fun rara e!!
 
D

Dessy

Guest
Tajmahal said:
Dessy, ki lo de?? O kan rerin shaa ni..........Ewo lo n je "loolu" ti nko ni ibi?? Oya mi lenu pe iwo nikan lo n wa si nu okun (thread) yi; baale re, Moliti Opushon nko?? :)
Broda mi Taju, o tojo meta o. Inu mi dun wipe oju yin ri odun titun yi o. Mo dele yin lana, won ni eyin ati omo opelenge kan jade. Iyalenu gbaa lo je fun mi. :excite
 
D

Dessy

Guest
Tajmahal said:
Haba! Esin yen aa ti poju ke!!! She o ranti wipe Ogagun Abasha fi 'fiimu' awon Ogagun Diya, Adisa, Olanrewaju, ati awon 'odaran' to ku han gbogbo aye latari 'kuupu' ti Abasha so pe oshele ni odun yen? Beeni a o ba wo 'fiimu' Abasha fun rara e!!
lol... :excite
 
Tajmahal

Well-Known Member
vince said:
Ma ma da loun o!Ibi yi wa je ile eko bi?Owu?!Eese?![/QUOTE]

E kare eyin Omo Oodua ti e n gbe ni oke okun! grinning: E o gbagbe orisun yin rara. Mi o ranti ojo ti mo gbo "Owu" ati "Eese" gbehin!!! Olohun yoo ke o!!!
 
Top