1. This site uses cookies. By continuing to use this site, you are agreeing to our use of cookies. Learn More.

YorubaEnglish, let's mix it up

Discussion in 'MOVIES IN AFRICAN LANGUAGES' started by vince, Mar 7, 2005.

Thread Status:
Not open for further replies.
 1. Simisola

  Simisola Well-Known Member

  Joined:
  Dec 4, 2003
  Messages:
  15,565
  Likes Received:
  73
  Dessy, nkan ti mo bere l'owo e ni ijosi nko nipa link yen nko?
   
 2. kolinzo

  kolinzo Oodua4life

  Joined:
  Apr 8, 2004
  Messages:
  7,000
  Likes Received:
  167
  Ewo le de fe ma mix up nsi sin hin? Eyin omo butter gbogbo.
   
 3. Peaches

  Peaches Registered

  Joined:
  Apr 25, 2006
  Messages:
  2,536
  Likes Received:
  13
  Bawo ni? Ki lo n bubble now? Iwo kan ma n se disappearing act e ni sha. Ki lo n happen now? Ki ni plans e fun weekend yi?:spiny:
   
 4. Peaches

  Peaches Registered

  Joined:
  Apr 25, 2006
  Messages:
  2,536
  Likes Received:
  13
  So o, o un ba mi soro nisin abi? Link wo lo n refer si? Okay...
   
 5. paj

  paj D JENGBORAN OF YORUBALAND

  Joined:
  Jan 15, 2005
  Messages:
  22,960
  Likes Received:
  141
  ..Eyin peepu mi..ee ni believe wipe mo lati re-cook obe ti mo se lana sha?Ah-mean...mo se obe yen tan..mo sheshe wa realise wipe mio fi curry sha ...mai guudness!smokin: No wonder ti obe yen lo n wa untastified bakan sha..U know?smokin: mba ti mo ni mba ti ran omo lo ra rice wa lati odo iya Bilikisu....oun maaa n'hook obe'e up koret koret..she'e get?smokin:
  Pa
   
 6. paj

  paj D JENGBORAN OF YORUBALAND

  Joined:
  Jan 15, 2005
  Messages:
  22,960
  Likes Received:
  141
  ..eyin she maa nlike lati maa ja ija igboro lojoojumo bayi na?:confused: Tio ye ki e maa set egsampu for awon Yoot ti o mbo leyin yin...eyin le ma koko fun oja mo ara beresi si maa yo eshe si omo inu yin?:confused: Ahh...Aunty...E cool tempa meeen :gnash..
  Pa :D
   
 7. Simisola

  Simisola Well-Known Member

  Joined:
  Dec 4, 2003
  Messages:
  15,565
  Likes Received:
  73
  nipa blog yen.smokin: :eyes
   
 8. Peaches

  Peaches Registered

  Joined:
  Apr 25, 2006
  Messages:
  2,536
  Likes Received:
  13
  Paj, o sure wipe o ye ki o ma je nkan to wa spicy be yen after surgery e sha? She ara e ti strong to ni? Oloun ma je ki ounje se e lese sa! Igbawo lo yi kuro ni ospitu na? Ofun loro, woobia, ereke ni shobu, pari olodo fun ra e! Bee n ti e ri! Arounje yo!sweat:

  By the way, mo wa happy lati find out wipe o wa okay o. O ye ko ri mi bi mo se wa worried ngba ti mo ka thread Tunde ni sha! Thank God o!

  So, ewo lo wa up to ni weekend yi?:spiny:
   
 9. Simisola

  Simisola Well-Known Member

  Joined:
  Dec 4, 2003
  Messages:
  15,565
  Likes Received:
  73
  Ko je ko wa worried now. Sebi Abike ati Iya Laje wan nibe. Wa ma toju re ni ile. Oje ko ti mon wipe onijekuje ni bobo yen. Orisirisi ni sin je. :roll
   
 10. kolinzo

  kolinzo Oodua4life

  Joined:
  Apr 8, 2004
  Messages:
  7,000
  Likes Received:
  167
  Omo ki lo n'sele now? Se o wa okay? Well, Omo boy kan ma jirate kiri ni men. Mo ni kin stop bye kin se wasup si eyin pipu mi. O de fe mo plans me fun wikendi yi, well mi o ni plans kankan sofar. Mo kan ma shill in the main time. Anyway, je kin ri gbo ti enitin ba n'sele now!
   
 11. Peaches

  Peaches Registered

  Joined:
  Apr 25, 2006
  Messages:
  2,536
  Likes Received:
  13
  Well...mo ma yo si padi mi kan lola. O so wipe nkan kan ma sele ni Grays area ni UK nbi so, Friday mi ti set niyen. Then, saturday yii ma le gan as per owanbe level. Mo ma ya gele mi bi no woman's business ni men! mo ni wicked traditional wear ti mo ma yo fun won so o ti wa guaranteed wipe emi ni mo ma je belle of the ball ni ojo saturday yen men.

  As per sunday, mo kan ma chill ni men! Maa try lati lo si church as pe mo miss e ni last week.
   
 12. kolinzo

  kolinzo Oodua4life

  Joined:
  Apr 8, 2004
  Messages:
  7,000
  Likes Received:
  167
  Mo ti n'ma so fun e 'pe won kin fi curry si'nu omi ti won ba n'se fun mimu. O ma n'surprise mi gan men. Se kin sendi recipe card bi won se ma n'se omi si e ni? BTW, Ounje mama'yabo ma n'dun gan. Oloun ni kan l'omo iru seasoning to ma n'fi si men. Try e wo, oo ni regreti e!
   
 13. kolinzo

  kolinzo Oodua4life

  Joined:
  Apr 8, 2004
  Messages:
  7,000
  Likes Received:
  167
  oh girl, iwo gangan lo da mo. Mo ti rii pe o ma n'like awon owanbe party, se o sa ti get ready awon molla t'o ma bere si spend sa? Make sure pe o painti be yen red o! Eyin ti Jandon ma paty gan. Eniway, omo boy ma yo s'oun ye ni ojo kan. Oh, je kin bere kwes-shon kan l'owo e, se busi lo ma wo lo si be ni abi train? Nitori mo gbo pe e ni restrictions gidi loun yen!
   
 14. Simisola

  Simisola Well-Known Member

  Joined:
  Dec 4, 2003
  Messages:
  15,565
  Likes Received:
  73
  Desola, mr. pro nko? Se dada l'owa sha? Mo hopu wipe ko ti bere si n foc up o?
   
 15. paj

  paj D JENGBORAN OF YORUBALAND

  Joined:
  Jan 15, 2005
  Messages:
  22,960
  Likes Received:
  141
  ..Orii mi kan nwu bi o se nki mi nbeun...:music-smi emi ni kan lo ki tan baun?:music-smi iwo elenu'u faya bi igba'a wara ...o mo nkan...dokita ni ki n maa mu 'clear liquid' mo ba si lo ra Hennessey...wo ba so wipe mio le mu iyen..imagine?:gnash Won wa so wipe clear liquid ti mo le mu ni bii ogi,custard..nkankan...mmmccchhewwwww!!!!!:gnash..well...mo manage lati mu iyen fun bii ijo marun nigbati mo kuro ni osipitu...Ana...mo din obe mo si wo amala pelu E O!
  Pa
   
 16. paj

  paj D JENGBORAN OF YORUBALAND

  Joined:
  Jan 15, 2005
  Messages:
  22,960
  Likes Received:
  141
  ...eeehn..but she Mama'Yabo ni delivery service?:confused: because iwo naa mo wipe Okada o kin wa si area ibiyi mo latigba ti awon boyz e ti waylay won...smokin:
   
 17. Peaches

  Peaches Registered

  Joined:
  Apr 25, 2006
  Messages:
  2,536
  Likes Received:
  13
  O ma n **** me off gan sha? Kini gbogbo nonsense ti o ask mi yi? Omo, o ye ko sun ni men!
   
 18. Peaches

  Peaches Registered

  Joined:
  Apr 25, 2006
  Messages:
  2,536
  Likes Received:
  13
  Bus sha? No o, train ni o but mo ma endeavour lati gan bus ni summer sha lati le grasp gbogbo goings - on. Restrictions sha? mi o gbo n pa e o.

  Omo, mo tush gan o but ti o ba di party awon temi mo ma n turaka gan ni. No holds barred, shey o get? Omo, mo ni lati lo si bureau de change ni lunch time lati lo se owo ti mo ma na men!

  Waa ri gbo later!
   
 19. Peaches

  Peaches Registered

  Joined:
  Apr 25, 2006
  Messages:
  2,536
  Likes Received:
  13
  Bobo yi, accused ni e o. Ni ibi ti awa ti n hold night vigil ti a n se adura kara kara fun recovery e ni iwo ti return sile ma je Amala ati Hennesy. Ejo e ko! But as per clear liquid level yen, won mo wipe omo oko ni e ni. O explain fun won wipe ni ibi ti o ti wa, Fufu is equals to clear liquid ni? Won ti damo, o ye ko fi ye won ni.

  But omo wa o, o ni lati take e easy o. ti o ba wa careful, wa kan lo yokun ni awon babes o de ni wo side e mo. O mo wipe awon bobo oni six pack lo ni town nisin?
   
 20. Simisola

  Simisola Well-Known Member

  Joined:
  Dec 4, 2003
  Messages:
  15,565
  Likes Received:
  73
  Omodesola, mo ti sun, mo de ti ji ni si yin. Se o ma d'aun ibere yen ni PMvilli? ;)
   
Thread Status:
Not open for further replies.

Share This Page