She Ki Ama So Ede Yoruba Nikan Ni Ibi Yi

vince

Well-Known Member
Oo gbadun iwo Vincie yiii.
Oya, pada si orun apaadi ti o ti nbo. Mo lero wipe esu ti fi oju re ri mabo...sweat:
El general,esu o si ni orun apaadi o!Owun at awon emewa re ti travel....
Mo fe sere de orun,nitori pe mo gbo pe party kan nsele nibe.
Wan ni awon angeli nse owambe party fun jesu,buddha ati orunmilla.Mo de gbo pe party yen ma gbona gidi gaaan ni.
Se el general a te le mi lo?Ti o ba le ko awon omoge NR bi melo kan dani,ki a lo baraje ni be jati jati.
Ni asiko yi,orun apaadi dry bi thread yi,so....sweat::spin2:
 
Gen Sani Abacha

Alaye mi Vinsoma, emi ati e ko o!
Maa jegbadun re lo layo ati alafia...smokin:
 
vince

Well-Known Member
Mo ti pinu pe mi o ni so ede geesi ni inu forum yi mo,lai ati lai lai!Mo le ma so yoobanglish o,sugbon ko si aye fun ede geesi lasan mo.
Mo fe ma se akosile ni ede abinibi ni igba gbogbo, lati eni lo.
Ni ati ijo ti wan ti bi mi,ti wan ba ni ki wan ko gbogbo akosile ni ede yoruba ti mo ti ko titi di ojo oni jo,mi o ro pe o le kun paper kan!
ITIJU GBAAAA! :thumbs_down:
Ejo mi si ko!Ni igba ti wan ba komi ni ede abinibi ni ile iwe.
Sugbon ko i ti pe ju.O ba ni,ko baje.Kiko si ni mimo.Atunse bere ni ati oni yi lo,ni orile ede NR Rebublic!
Mo si ti bere si ma ko script ni ede yooba,o si n'dun mo mi gidi gaaani!grinning:

Eni ti o ba dun mo,ki o lo be s'odo!smokin:
 
peculiar

Ko dun mo mi o, alagba Finsi! Sugbon ko si odo kankan ni adugbo ti mo n gbe!sweat:sweat:
 
Top