She Ki Ama So Ede Yoruba Nikan Ni Ibi Yi

peculiar

Well-Known Member
Omidan Pekuliar, eetiri ? eebu bi ti bawo?
Mo nsa e ni o, faaini geeli lukin segzy ni mo fe so o...;)
O da, mo gba yin gbo!:fing02:

Ere yoruba de n wu mi i wo sha. :redface Sugbon oorun ti n kun mi, ise de wa ni aaro ola. help:

O dabi wipe, emi n lo sun niyen o. O daaro o, eyin ara mi lori NR. Ipade wa bi oyin o...okookan la o ji o! Amin. :fing33:
 
Gen Sani Abacha

O daaro o aburo mi owon, ka sun layo, ka ji layo o, Amin.

Ebi dee ti e npa mi sa....huuuuuuuuuun, maa lo wa nkan je ki nto sun.

Eyin ara NR, mo ri yin naa...:)
 
paj

Well-Known Member
O daaro o aburo mi owon, ka sun layo, ka ji layo o, Amin.

Ebi dee ti e npa mi sa....huuuuuuuuuun, maa lo wa nkan je ki nto sun.

Eyin ara NR, mo ri yin naa...:)
...ah ha..wah na O..Generah...kii she Gambari ni e ni?:gnash bai di we(by the way :D),share mi ninu owo ti o ko je ni igba Ijoba re da?:knuck
Pa
 
Gen Sani Abacha

Well-Known Member
...ah ha..wah na O..Generah...kii she Gambari ni e ni?:gnash bai di we(by the way :D),share mi ninu owo ti o ko je ni igba Ijoba re da?:knuck
Pa
Ti o ba fe gba sia tire, lo ba onku Sege alias baba Iyabo soro, owo re ni gbogbo owo naa wa bayii ooooooooo.
 
vince

Well-Known Member
Ojo iku lojo isinmi.
Nkan to ba wu onikaluku ni ko fi ori ara re se.
E je ki onikaluku sogba e.
Oto oro, omo iya isokuso ni o.
Inu rere o se fowo ra.

Eyin eyan, e ni lo si orile ede ti wan npe ni "Talikania" fun greener pastures o. Ase!

O tun digba!
 
Top