• Naija Rules! has been around since 2003, providing a hangout for the fans of Nigerian and African movies. Our members were in the forefront of the spread of movies from Africa to the world.

She Ki Ama So Ede Yoruba Nikan Ni Ibi Yi

Gen Sani Abacha

Well-Known Member
E ku osu tuntun o, e de kuu ipalemo odun Keresimesi, osu to'nbo, ipari odun, a ba gbogbo wa layo ati alafia, ni oruko Jesu, Amin.
 
Gen Sani Abacha

Well-Known Member
Ekaaaro o, eyin ara abule wa ni ahin o.
Se daadaa ni gbogbo yin wa sa ?
Mo ki yin o, tile tode, toko taya, tobi tomo.

Odigba kan naa.
 
Gen Sani Abacha

Well-Known Member
Eyin ara wa, mo tun de ni ahin o. Mo ni ki nfi to yin leti ni o. E gbo ewi igbalode(rap), ti e la fi ko awon omo kekeeke, ni abidi Yoruba. Oun re ni bi: Abidi.

E seun.

O digba kan naa.
 
kolinzo

Well-Known Member
O daa be, General Saani. O ye ki won se katuunu fun awon omo kekere ni Yooba gan. N je o ti e wa?
 
Gen Sani Abacha

Well-Known Member
Eyin ara mi, e gba yi yewo. Awon alawada ile wa kan ti se ongbufo ere sinnima Irinajo si Ile Amerika ie 'Coming to America', lati ede Geesi si ede wa Yoruba. Elere alawada, eniyan Adulawo-Amerika, Ogbeni Eddie Murphy lo ni ere ohun, o si gbe e jade ni odun 1988.

E o ri i wo ni biyi: Aworan Sinnima Irinajo si Ile Amerika

E seun.
 
kolinzo

Well-Known Member
O seun gan, General Saani! Ere Irinajo Si Ile Amerika ni ede Yooba larinrin! O pani ni erin lopo lopo; o pani ni erin arinfeeku! Ogbeni Edi Mofi ni oyaya gan. Asiko ti wa de bayi fun eni ti o ba ni opolo abi ogbon ati y'ohun pada lati se owo (do-do) sinima bii ti Irinajo Si Ile Amerika. Owo (re-mi) tabua be ninu re!
 
Otitio oro gan-an lo sp yen. O ku si owo aweon elere Yoruba aye ode oni.
 
Gen Sani Abacha

Well-Known Member
Eyin eniyan mi, e ku deedee iwo yi o, e de kuu ipalemo odun keresimesi to nbo lona o.
Mo kan fe polongo 'Egbe Onkawe Ede Yoruba' ni orile-ede Naijiria. Eka 'Egbe Onkowe Odo Orile-Ede Naijiria', ni won nse. E le ye won wo nibiyi: Egbe Onkawe Ede Yoruba.
 
Eleyi dara lopo lopo. Sugbo aaahn...Yoruba kika mi o danmoran (O ma se o). Lai fa oro gun, nkan be ni saiti yen. Mo ma gbiyanju lati ma kan sibe ni igba gbogbo kin le ko eko ti o ma gbe Yoruba kika me si oke. Jenera Saani, o seun lopolopo.
 
Ogbeni Kolinzo, a ki i dupe ara en o. Ki Oluwa ran e lowo ninu eto iwe kika ni ede Yoruba, Amin o, Jesu Kristi.
 
Top