Gen Sani Abacha
Well-Known Member
E ku osu tuntun o, e de kuu ipalemo odun Keresimesi, osu to'nbo, ipari odun, a ba gbogbo wa layo ati alafia, ni oruko Jesu, Amin.
E ku osu tuntun o, e de kuu ipalemo odun Keresimesi, osu to'nbo, ipari odun, a ba gbogbo wa layo ati alfia, ni oruko Jesu, Amin.
E ku osu tuntun o, e de kuu ipalemo odun Keresimesi, osu to'nbo, ipari odun, a ba gbogbo wa layo ati alfia, ni oruko Jesu, Amin.
A o gb'oyinbo nibi o...e ba wa so ede abinibi, e seun!!!What?
OP seun Ogbeni Kolinzo. Mi o lero wipe katuunu ni ede Yoruba fun awon omo were wa ni bayi.O daa be, General Saani. O ye ki won se katuunu fun awon omo kekere ni Yooba gan. N je o ti e wa?
OP seun Ogbeni Kolinzo. Mi o lero wipe katuunu ni ede Yoruba fun awon omo were wa ni bayi.
Otitio oro gan-an lo sp yen. O ku si owo aweon elere Yoruba aye ode oni.O seun gan, General Saani! Ere Irinajo Si Ile Amerika ni ede Yooba larinrin! O pani ni erin lopo lopo; o pani ni erin arinfeeku! Ogbeni Edi Mofi ni oyaya gan. Asiko ti wa de bayi fun eni ti o ba ni opolo abi ogbon ati y'ohun pada lati se owo (do-do) sinima bii ti Irinajo Si Ile Amerika. Owo (re-mi) tabua be ninu re!
O ye ki awon elere Yoruba le ba iru Grafikdon sise, ke ?Hmm!! Eni o ba ni opolo bii ti Grafikdonu ki o tete bere re. Omo weere po ni ile karo ojire ti won ma gbadu ere bee!
O ye ki awon elere Yoruba le ba iru Grafikdon sise, ke ?
Hmmmmm...O ye ki awon ojogbon onimo-ede Yoruba ke si ogbeni Tunde Kelani ati awon eniyan bee yen, ki won wa nnkan se si.Emi naa ro bee! Sugbon gbogbo irinkerindo, a nwe owo s'otun ati s'osi, o ni je ki a mo ibi ti oju aago wa!
Eleyi dara lopo lopo. Sugbo aaahn...Yoruba kika mi o danmoran (O ma se o). Lai fa oro gun, nkan be ni saiti yen. Mo ma gbiyanju lati ma kan sibe ni igba gbogbo kin le ko eko ti o ma gbe Yoruba kika me si oke. Jenera Saani, o seun lopolopo.Eyin eniyan mi, e ku deedee iwo yi o, e de kuu ipalemo odun keresimesi to nbo lona o.
Mo kan fe polongo 'Egbe Onkawe Ede Yoruba' ni orile-ede Naijiria. Eka 'Egbe Onkowe Odo Orile-Ede Naijiria', ni won nse. E le ye won wo nibiyi: Egbe Onkawe Ede Yoruba.
Ogbeni Kolinzo, a ki i dupe ara en o. Ki Oluwa ran e lowo ninu eto iwe kika ni ede Yoruba, Amin o, Jesu Kristi.Eleyi dara lopo lopo. Sugbo aaahn...Yoruba kika mi o danmoran (O ma se o). Lai fa oro gun, nkan be ni saiti yen. Mo ma gbiyanju lati ma kan sibe ni igba gbogbo kin le ko eko ti o ma gbe Yoruba kika me si oke. Jenera Saani, o seun lopolopo.