• Naija Rules! has been around since 2003, providing a hangout for the fans of Nigerian and African movies. Our members were in the forefront of the spread of movies from Africa to the world.

Yoruba Proverbs: owe Kanti Kanti

Status
Not open for further replies.

Moremi

Active Member
1. oun to yeni lo yeni.. okun orun o ye adiye.. o de ye adiye.. eni ti o dimu loju ma ti.
translation... rope for neck no fit chicken.. but if it fit am.. na the person wey carry am go shame.

2. a n pe e ni ole.. o n gbe omo eran jo.
translation... we are calling u theif..u are dancing with goats child.
 

queen2

Well-Known Member
Eni abalaba ni baba,(translation) the person we met in the village is the father
Gbogbo oun ton dan ko ni wura,(translation) all that glitter is not gold
 

Tajmahal

Well-Known Member
olusegun bayode said:
ologbon ni jo omoran ni si nmo am i right?

Segun, Olusegun, Oluwasegun, emelo ni mo pe e? Ewo l'onje 'am i right'? Ta lo be e ni Geesi so?? :excite Ka ma fa oro gun, beeni owe yen ri..............Ose omo daadaa!
 

Tajmahal

Well-Known Member
Anthonia said:
Oo right sugbon o try die.
Bi owe bi owe ni a nlu ilu agidigbo, ologbon ni njo omoran ni si mo.

Ah! Omo Oodua gidi ni e, mo gba ti e!!! O kare ti oo gbagbe orisun e! bgrin:
 

Anthonia

Member
Ajanaku koja a mo ri nka firi, ti a ba ri erin k'a so wipe a ri erin.

Imado i ba se bi elede a ba ilu je, eru iba j'oba eniya iba ti ku ikan.

o ya eyin omo Oodua, translations please, Tani mo o ko wa so itunmo awon owe wonyi.
 

bollyd

moda b4 moda!
"akuku gbodowi ba'le ile su sape"

"ai fini peni ai feyan peya lo mu ara ok san bante wolu"

"e je ki a pe were loko iyawo koje ki ari'mu mi"
 

vince

Well-Known Member
Awon baba wa ni won ma pa owe yi.Won ni;
"Kuriositi,lo pa ologbo....abi okete de ni".
Mi o ranti mo,sugbon owe n'la ni owe nan!
 

bliss

Member
Ajanaku koja a mo ri nka firi, ti a ba ri erin k'a so wipe a ri erin.

Imado i ba se bi elede a ba ilu je, eru iba j'oba eniya iba ti ku ikan.

o ya eyin omo Oodua, translations please, Tani mo o ko wa so itunmo awon owe wonyi.


This proverb is simply translated thus: when the head of an household dies and an invalid takes over, sorrow begets sorrow

Imado i ba se bi elede a ba ilu je, eru iba joba eniyan iba ti ku ikan

Simply translated : when the head of an household dies , and an invalid takes over, sorrow begets sorrow
 
Status
Not open for further replies.
Top